course outline and references nce€¦ · course content for nce yoruba department adeyemi college...

16
COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO YORB COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE KO O S KD DN KN-N-N SIME ST KIN-IN-NI KRE DT IP YOR1 111 kto Yorb 2 C YOR1 112 lo d Yorb 2 C YOR1 113 fr s Ltro Alohn Yorb 2 C YOR1 114 tn ti Yorb 1 E YOR1 115 tumo d 1 E 6C + 1E = 7 KO O S KD DN KN-IN-N SIME ST KJ KRE DT IP YOR1 121 Mofo lo j Yorb 2 C YOR1 122 Fne tk ti Fono lo j Yorb 2 C YOR1 123 fr s Ltro pile k Yorb 2 C TOTAL 6 K KO O S KD DN KEJ SIME ST KIN- IN-NI KRE DT IP YOR1 211 Grm Yorb I 2 C YOR1 213 Er-One pile k Yorb 1 C YOR1 214 gbo n ko ni n Yorb 2 C YOR1 215 gbo n wad n Yorb 2 C TOTAL 7 KO O S KD DN KEJ SIME ST KJ KRE DT IP YOR1 221 Grm Yorb II 1 C YOR1 222 gbye w Ie -n Ltro ti mo wo l-d 2 C YOR1 223 tn rs pile k Yorb 1 C YOR1 224 gbo n ko ni n Yorb 1 C YOR1 225 fko ra Ie Yorb 2 TOTAL 7 KO O S KD DN KE TA SIMST KN- IN-N KRE DT EDU 311 (KO M-N-W-O ) 6 YOR1 324 Ie kne-Education 323 2 YOR1 214 gbo n ko ni n Yorb 2 YOR1 215 gbo n wad n Yorb 2

Upload: others

Post on 30-Jul-2020

16 views

Category:

Documents


9 download

TRANSCRIPT

Page 1: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

YORUBA COURSE OUTLINE AND REFERENCES

NCE

KO O SI KOODU ODUN KIN-IN-NI SIME SITA

KIN-IN-NI

KIRE DIITI IPO

YOR1 111 Akoto Yoruba 2 C

YOR1 112 Ilo Ede Yoruba 2 C

YOR1 113 Ifaara si Litireso Alohun Yoruba 2 C

YOR1 114 Itan ati Asa Yoruba 1 E

YOR1 115 Itumo Ede 1 E

6C + 1E = 7

KO O SI KOODU ODUN KIN-IN-NI SIME SITA

KEJI

KIRE DIITI IPO

YOR1 121 Mofo lo ji Yoruba 2 C

YOR1 122 Fone tiiki ati Fono lo ji Yoruba 2 C

YOR1 123 Ifaara si Litireso Apile ko

Yoruba

2 C

TOTAL 6

K

KO O SI

KOODU ODUN KEJI SIME SITA KIN-

IN-NI

KIRE DIITI IPO

YOR1 211 Girama Yoruba I 2 C

YOR1 213 Ere-Onise Apile ko Yoruba 1 C

YOR1 214 Ogbo n Iko ni ni Yoruba 2 C

YOR1 215 Ogbo n Isewadii ni Yoruba 2 C

TOTAL 7

KO O SI KOODU ODUN KEJI SIME SITA KEJI KIRE DIITI IPO

YOR1 221 Girama Yoruba II 1 C

YOR1 222 Agbeye wo Ise -ona Litireso ati

Imo Isowo lo-ede

2 C

YOR1 223 Itan Aroso Apile ko Yoruba 1 C

YOR1 224 Ogbo n Iko ni ni Yoruba 1 C

YOR1 225 Ifiko ra Ise Yoruba 2

TOTAL 7

KO O SI KOODU ODUN KE TA SIMESITA KIN-

IN-NI

KIRE DIITI

EDU 311 (KO MO-N-WO-O ) 6

YOR1 324 Ise Akanse-Education 323 2

YOR1 214 Ogbo n Iko ni ni Yoruba 2

YOR1 215 Ogbo n Isewadii ni Yoruba 2

Page 2: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

TOTAL 7

KOOSI KOODU ODUN KE TA SIME SITA

KE TA

KIRE DIITI IPO

YOR1 321 Imo E ro ati Saye nsi Yoruba 1 E

YOR1 322 Ewi Apile ko ati awon Akewi

Yoruba

2 C

YOR1 325 Ise -gbigbooro lori Litireso

Alohun Yoruba

2 C

YOR1 215 Igbe-aye ati Awujo Yoruba 2 E

TOTAL 4C+1E=5

Akiyesi – Itupale: Kirediiti 25 ni a nilo lati fi gboye jade

• Koosi dandan-lowo-ori: Kirediiti = 30

• Koosi oni-sisa-riro: Kirediiti = 02

Apapo = 32

Page 3: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

ILA-ERO FUN EDE (YOR1)

ODUN KIN-IN-NI SIMESITA KIN-IN-NI

YOR1 111 AKOTO YORUBA (KIRE DIITI 2) C

Bibojuwo itan bi ede

Bibojuwo itan bi ede Yoruba se di kiko sile nipa akitiyan Bowdich, Kilham,

Raban, Crowther, Gollmer, Townsend, Lepsius, Venn etc.

Apero lori Akoto Yoruba ni odun 1875, ati orisii aayan lori akoto titi di oni-

akitiyan ti Bamgbose, 1966, 1974 ati Ede Iperi I & II.

Atenumo gbodo wa lori, akoto iwoyi pe lu asekara ise lori re .

Eka-ede Yoruba b.a. Egba, Ijebu, Akoko, Ikale , abbl.

REF: Abati, O. (1994) Akoto Yoruba Ode-Oni. Ibadan: Unique Publishers

Limited.

Arohunmo lase, O. (2000). Ilo Ede Yoruba. Ninu Iwe E ko Ijinle Yoruba fun

awon Ake ko o ati Oluko . Ondo. Crofes Press and Publisher.

Bamgbose, A. (1974) Yoruba Orthography

Olumuyiwa, T. (1994) Awon E ka-Ede Yoruba I. Akure. Montem Paperbacks

YOR1 112 ILO EDE YORUBA (KIRE DIITI 2) C

Awon ede amulo ati ilo won. b.a. ede awako , ede iyalo ja, o na-ede ati aroko

abbl.

Sise idanrawo daadaa lori gbogbo awon koko oke yii bi o ti je yo ninu afo

Yoruba.

E ya aroko

Kiko aroko daadaa lori e ya kookan

E ya Akaye/Iwe Kika

Pipajuba Lori imo o se akaye

REF: Awolaoye, S. (2008). Iko ni Ni Ilo Ede Yoruba. Oro: JOF Global Production

COED.

Raji,m S.M., Fasehun, M.A., Ajayi, F. T. ati Efemini C. O. (2017) Oribande

YOR1 113 IFAARA SI LITIRESO ALOHUN YORUBA (KIRE DIITI 2) C

Itan idagb soke Litireso Alohun Yoruba

Awon abuda adani Litireso Alohun Yoruba

Awon eya Litireso Alohun ati ipinsi-iso ri

Abuda adani o ko o kan won

Ise amuse ni iyara ife rokede ni a gbo do tepele mo

REF: Raji, S. M. (aiy) (2009). Okan-o-jo ka Ewi Alohun Yoruba. Ibadan: Alafas

Nigeria Company.

Odeajo, L. (1992). Atupale Litireso Atenude nu. Ibadan: Alafas Nigeria

Company

Abimbo la, W. (2006). Ijinle ohun Enu Ifa: Apa Kin-in-ni. Ibadan:

University Press PLC

Abimbo la, W. (2006). Ijinle ohun Enu Ifa: Apa Keji. Ibadan:

University Press PLC

Page 4: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

Ajuwo n , B. (1981). Iremoje Ere Isipa Ode. Ibadan University

Press PLC

Ajuwo n , B. (1989). Ogbere. Ibadan University

Press PLC

YOR 114 ITAN ATI ASA YORUBA (KIRE DIITI 1) E

Orirun Yoruba

Awon ilana ifinimole-awujo b.a. igbeyawo, omo bibi ati ito ju omo, eto

Iso mo loruko, E ko ile – iwa omoluabi, ikini abbl.

Ere sise abinibi

Awon odun ibile ati awon orisa ile Yoruba.

REF: Olu D. ati A Je je (1968): Awon Asa ati orisa Ile Yoruba. Ibadan: Onibonije

Press.

Ogunranti, J. I. (2012) Itan ati Asa Yoruba. Ibadan: Alafas Nigeria Company

Adeoye C. L. (1980), Asa ati Ise Yoruba, Ibadan: University Press.

YOR 115 ITUMO EDE (KIRE DIITI 1) E

Ofin ti o de itumo ede

• Eya itumo ede

• Iyiletapada

• Bi a se nlo e ya mejeeji

• Amuse ise lori itumo ede

• Titumo awon ayo ka ede Geesi si Yoruba, ati ti Yoruba si Geesi

REF: Adeoti, G. B. O. (2006)."Aayan Ogbufo ” Ninu Oyewo le Arohunmo lase, (O. I)

Iwe E ko Ijinle Ede Yoruba fun awon ake ko o ati oluko . Iwe

Keji. Ondo. Croffes Press Publishers.

Akinbo , R. (2006). "Aayan Ogbufo tabi Titumo Ede” Ninu Oyewole

Arohunmo lase, (O. I) Iwe E ko Ijinle Ede Yoruba fun awon ake ko o ati

oluko . Iwe Keji. Ondo. Croffes Press Publishers.

Awobuluyi, O. (ed) (1990) Yoruba language Meta (Ede Iperi Yoruba) Vol. 11.

Ibadan: University Press PLC

Babalola, A. (1975). Aayan Ogbufo : Lagos Longman Pub. Comp.

Page 5: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

ODUN KIN-IN-NI SIMESITA KEJI

YOR1 121 MOFO LO JI YORUBA (KIRE DIITI 2) C

Ohun ti Mofoloji je

Ohun ti Mofiimu i se

Idamo Mofiimu kan

Awon eya Mo fiimu (Mo fiimu afarahe, Mo fiimu adaduro)

Awon e da-moofu ninu Yoruba

Oriki awon o ro

Ilana Ise da-o ro , eyi ni afomo -ibe re , afo mo -aarin, apetunpe, isodoruko abbl.

REF: Taiwo O. (2006). Mofo lo ji: Atunse Keji: Ibadan: Universal Akada Books

Adekeye, F. B. (2016). Girama Tuntun ni Ede Yoruba. Aba; Oluwole

Printing Co.

YOR1 122 FONE TIIKI ATI FONO LO JI YORUBA (KIRE DIITI 3) C

Awon e ya-ARA IFO /ISO RO

Ona igbe awon iro jade

Apejuwe ati ipin-si-iso ri awon iro fawe li ati ko nsonanti

Didariko awon iro fawe li ati ko nsonanti

Idako/Adako fone tiiki

Foniimu ati e da won

Idako/Adako foniimu

Awon iro ohun

Ihun silebu

Ipaje ati Isunki

Aranmo

Ijeyopo fawe li

Ankoo fawe li

Iyopo fawe li

Ise amuse ni iyara ife rokede ni a gbodo tepele mo

REF: Owolabi, K. (2011) Ijinle Itupale Ede Yoruba (1). Ibadan Universal Akada

Books Nigeria Limited.

Awobuluyi, O. (1990) Yoruba MetaLanguage (Ede Iperi Yoruba) Lagos:

Nigerian Educational Research and Development Council. Vo. 11.

Bamgbose, A. (1967) A short Yoruba Grammar, Ibadan: Heinmemann

Educational Books Ltd.

Bamgbose, A. (1990) Fonolo ji and Girama Yoruba Ibadan: University Press.

Oyebade, F. (2008) A course in Phonology (2nd Edition). Ije bu-Ode

Shebiotimo Publications.

Yul-Ifode, S (2007). A Course in Phonology. Port Harcourt: University of

Port Harcourt Press.

YOR1 123 IFAARA SI LITIRESO APILE KO YORUBA (KIRE DIITI 1) C

Itan Idagbasoke Litireso apile ko Yoruba

Awon iyato ti o wa laarin Litireso Alohun Yoruba ati apile ko

Awon eya Litireso apile ko b.a. Ewi, itan-aroso ati Ere-onise

Yiyan iwe ko o kan lori eya itan-aroso, Ewi ati Ere-onise

Page 6: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

REF: Olatunji, O. O. (1982). Ewi Adebayo Faleti. Iwe Kinni. Heinemann. Ibadan.

Akinwumi I., (2007) O Le Ku. University Press Limited Ibadan.

Akinwumi I. (2015). Efunsetan Aniwura. Iyalode, Ibadan. University Press

Limited Ibadan.

.

Page 7: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

ODUN KEJI SIMESITA KIN-IN-NI

YOR1 211 GIRAMA YORUBA I (KIRE DIITI 2) C

Ohun ti a le tumo Girama si

Ipin siso ri o ro

O ro.-Oruko

O ro -ise

Aseranwo O ro -ise

Aropo Oruko Afarajoruko

Eyan (pe lu Asapejuwe) E yanruko

E yanse/O ro Apo nle

O ro -Ato kun

O ro -Asoropo

(Ki oluko tepele mo ORIKI, bi a ti se le da won mo ati ipin – siso ri won)

REF: Adekeye, B (2016) Girama Tuntun ni Ede Yoruba. Aba: National Institute

for Nigerian Languages.

Ajiboye, O. (2003) GIrama Ede Yoruba Ode Oni. Ilorin: Essentials of

Yoruba

Awobuluyi, O. (1982), Essentials of Yoruba Grammar. Ibadan: UP Ltd.

YOR1 213 ERE-ONISE APILE KO YORUBA (KIRE DIITI 1) C

Ohun ti Ere-onise Yoruba je

Awon eya Ere-onise Yoruba

Kiko ako jinle lori e ya meji o kere tan (ge ge bi ere-Onise adaleri itan gidi,

adaleri e honu, iselu, o tele muye, afe dase fe /ajemo se le -awujo), ati titepele mo

ogbo n iso tan, ahunpo itan, iparoko, ifiwawe da-itan, ilo ede ati koko-o ro itan.

REF: Litireso Yoruba (2012). E ka E ko Ede Yoruba Federal College of Education,

Osiele, Abeokuta, Ipinle Ogun.

Omoniyi Ajiboye (2002) Litireso Yoruba Ifaara. Ilorin: EMA Books.

Ogundeji P. A. (1992). External Studies Programme. Yoruba Drama 1.

University of Ibadan.

Adejumo , A. G. (2015) Yoruba Drama II. External Studies Programme.

Yoruba Drama 1. University of Ibadan.

Clark, E. (1979). Hubert Ogunde: The making of Nigerian Theatre. Oxford:

O.U.P.

Crow, B. 1983 Studying Ddrama. U.K. Longman Group Ltd.

Ogunbiyi Yemi (1981). Drama and Theatre in Nigeria: A critical source book

– Lagos: Nigeria Magazine.

Adebo wale, O. (1999) Ogbo n Onko we Alatinuda. Lagos: The Copstone

Publications.

Iso la, A (1970). Efunstan Aniwura. Ibadan: Oxford University Press.

Page 8: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

Omoniyi Ajiboye (2003) Litireso Apile ko Yoruba Ifaara si Ere-Onis e Yoruba.

Ilorin: EMA Books Nig. Publishers.

Oladejo Okediji (1973) Re re Run. Ibadan: Onibonoje Press and Book

Industries (Nig.) Ltd.

Olabimtan, A. (1966). Oluwa lo Mejo Da. Lagos: Macmillan & Co. (Nigeria)

Ltd.

Iso la, A (1979). Olu Omo. Ibadan: Onibonoje Press and Book

Industries (Nig.) Ltd.

Iso la, A (2009). Aye Ye Won Tan. Ibadan: DB Martoy Books

Iso la, A (1973). Re re Run. Ibadan: Onibonoje Press and Book

Industries (Nig.) Ltd.

YOR1 214 OGBO N IKO NI NI YORUBA I (KIRE DIITI 2) C

Sise asaro lori Yoruba ti o wa ninu korikuloomu orile-ede, eyi ni Eto E ko Ipile

1, 3, 4 – 6, 7 – 9

Eto ise ati ilana ise ijokoo kan

Ilana ipile fun Iko ni ati Kiko ede Yoruba bi ede ako ko -eni

Awon eto ilana fun Yoruba bi ede akoko eni; Eyi ni ikoni ni awon orisiirisii

ori-o ro ninu ede Yoruba, (awon e ya imo eda ti Fonoloji ati Girama), Litireso

ati Asa.

Amuse-ise ni iyara ife rokede ati ifeeyan-perete-ko ni pon dandan.

REF: Adebayo A. (1996) TEE 335 Yoruba Language and Literature Methods

(Ogbo n Iko ni lede ati Litireso Yoruba) Ibadan: University, Ibadan.

Adebayo A. (2000) TEE 335 Yoruba Methods (Ogbo n

Iko ni ni Yoruba) Ibadan: Centre for External Studies University of

Ibadan.

Ade Oginni (1990) Ko mo-N-wo-o ni Ede Yoruba. O sun: Faith

Communication Ltd.

Awolaoye Olayinka (2008). Iko ni ni Ilo Ede Yoruba oro: JOF Global

Production COED.

Omoniyi Ajiboye (2002) E ko ati Iko ni ni Ede ati Litireso Yoruba. Lagos:

TOMFETES Publishers Company.

YOR1 215 OGBO N ISEWADIII NI YORUBA (KIRE DIITI 1) C

Ohun ti ise iwadii je

Awon e ya ise iwadii b.a. asapejuwe, adaleri-itan gidi, adaleri-asewo/akiyesi

abbl.

Iwulo ati laarija ise iwadii

O na isakojo deeta (akojo ede faye wo)

Isagbekale at i ibeere iwadii (dahun-bi-o-se-fe ati dahun-bia-se-la-a-sile )

Page 9: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

Ito kasi ati akojo oruko iwe (lilo eto ilana ti American Psychological

Associaition)

REF: Omoniyi Ajiboye (2002) Ogbo n Iwadii Imo Ijinle Yoruba (Research

Methods). Ibadan E.M.A. Publishers.

Adeke mi Adebiyi (2004) Ise Apile ko (Ato na Ake ko o ), Federal College of

Education Abeokuta: Library Publishers.

Adeleke D. ati Adebiyi Ke mi (1998) Ogbo n Isewadii ni Ede Yoruba. Ibadan

Sam Bookman Publishers.

Bamgbose Ayo (ed) (1992). Yoruba MetaLanguage (Ede Iperi) Yoruba Vol.

II. Ibadan, University Press.

Ogunbiyi, M. B. (1992). Understandinmg Research in the Social Sciences,

Ibadan University Press PLC.

Olunlade Taiwo (1994). Abo Iwadii (Research Reports) Apa Kin-in-ni (Part

One, Lagos, Surety Ventures Nigeria Limited.

Page 10: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

ODUN KEJI SIME SITA KEJI

YOR1 221 GIRAMA YORUBA II (KIRE DIITI 1) C

Apola b.a. Apola o ro -oruko, apola o ro -ise, apola o ro -apo nle (apola-apo nle),

apola o ro -ato kun abbl

Oriki, Idamo, Ihun ati Lilo, Kiko ako jinle lori orisiirisii awe -gbolohun b.a.

olori awe -gbolohun, awe -gbolohun afarahe

E hun akiyesi alatenumo

Gbolohun: ihun ati e ya – ipin-si-iso ri ihun ati lilo

Awon Iso ri Girama eyi ni asiko ati iba-ise le

REF: Adeke ye, B (2016) Girama Tuntun ni Ede Yoruba. Aba: National Institute

for Nigerian Languages.

Ajiboye, O. (2003) GIrama Ede Yoruba Ode Oni. Ilorin: Essentials of

Yoruba

Awobuluyi, O. (1982), Essentials of Yoruba Grammar. Ibadan: UP Ltd.

YOR1 222 AGBEYEWO ISE -ONA LITIRESO ATI IMO ISOWO LO-EDE

(KIRE DIITI 2) C

Ohun ti agbeye wo ise -ona Litireso je

Lilo imo agbeyewo ise-ona Litireso lati setupale awon ise asayan kan.

Ohun ti imo isowo lo-ede je

Ipa imo eda-ede ninu ako jinle imo isowo lo-ede

Eto Olooro ati Eto Onibuu

Idamo ati amulo abuda- isowo lo-ede

Iyapa ninu imo isowo lo-ede

Imo -riri-ewa ninu isowo lo-ede

REF: Ajibade, G. O. ati Raji, S. M. (2013). Isowo lo-Ede Ewi Alabi

Ogundepo , Akure : Masterprint Publishers.

Olabimtan, A. (1980). Ogbo n Itopinpin EwiYoruba. Lagos: Macmillan

Nigeria Publishers Limited.

O pe feyitimi, a. (1997). Tio ri ati isowo lo-ede. Ile-Ife ; Obafemi Awolo wo

University press.

Raji, S. M. (2011). “Isowo lo-ede inu orin ati Ewi Alabi Ogundepo: Iyapa

Ge ge bi ona Ede, E gin: Jo na Ise Akada ni ede Yoruba, Adeyemi

College of Education, Ondo.

YOR1 223 ITAN AROSO APILEKO YORUBA (KIRE DIITI 1) C

Ohun ti itan aroso Yoruba je

Awon eya itan aroso Yoruba b.a. o tele muye, adaleri-itan-gidi, feyiko gbo n.

Kiko akojinle o kere tan orisii e ya meji (agbogoyo, agbogoyo titu, igbalode),

ati tite pele mo awon ogbo n iso tan, ilo-ede, iparoko, ahunpo -itan, ifiwawe da-

itan abbl.

F aturoti, O.R. (2010). Lori Oke Saikofilo Ile-Ife : Adegbite Press.

Adegbodu, O.D. (2010) Ile O re O yo : Odumati press

Page 11: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

Folake , A.(2017). Panpe Abo. Ibadan Graceville publishers

Okediji, O. (1971). Agbalagba Ako n. Ibadan Longman Nig. Ltd

Fagunwa, D.O, (2005). Ogboju Ode ninu Igbo Irunmole . Ibadan : Nelson

publisher.

Ogunsina B. (1992). The Development of the Yoruba Novel (1930 – 1975),

Ilorin: Gospel Faith Mission Press.

Fagunwa B. O. (1938) Ogboju Ode Ninu Igbo Irunmole , London: New York

T. Nelson.

T. M. Olawuwo ati A. A. Ato lagbe (2016) Idide ati Idagbasoke Litireso

Apile ko: Lagos Kingdom Heritage Printing sand Publication

Ventures.

Akinlade Bo la (1976) Owo E je , Ibadan. Onibonoje Press and Book Industries.

YOR1 224 OGBO N IKO NI NI YORUBA II (KIRE DIITI 1) C

Awon ohun-elo-iko ni

Igbelewo n

Ilo Yoruba fun iko ni ninu awon ise miiran.

Ilana yiyan iwe asayan

Mimojuto awon iwe iranti ti ile-iwe

Ifeeyan-perete-ko ni ati irin-ajo-ajemo -iko ni

Iko ni-alajumo -sise

REF: Adebayo A. (1996) TEE 335 Yoruba Language and Literature Methods

(Ogbo n

Iko ni lede ati Litireso Yoruba) Ibadan: University, Ibadan.

Adebayo A. (2000) TEE 335 Yoruba Methods (Ogbo n

Iko ni ni Yoruba) Ibadan: Centre for External Studies University, of

Ibadan.

Ade Oginni (1990) Ko mo-N-wo-o ni Ede Yoruba. Osun: Faith

Communication Ltd.

Awolaoye Olayinka (2008). Iko ni ni Ilo Ede Yoruba oro: JOF Global

Production COED.

Omoniyi Ajiboye (2002) E ko ati Iko ni ni Ede ati Litireso Yoruba. Lagos:

TOMFETES Publishers Company.

YOR1 225 IFIKO RA ISE YORUBA (KIRE DIITI 2) C

Isakojo awon ise owo abinibi

Idamo ati awon ilo die lara awon ohun elo abinibi yii b.a. aro dida, irin riro

abbl.

Ijiroro lori ile isura nnkan ise nbaye

Orisii imuse ninu Ere-onise-tiata, iweundere, - alaga ijokoo, adari eto abbl.

Onkowe alatinuda ati ise re

Abuda adani ise onkowe alatinuda

Ilana to ro de ise atinuda Ewi, Itan aroso ati Ere-onise

Ebun So ro so ro

Page 12: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

Amuse ise gunmo lori ise onko we alatinuda

REF: Adeoye C. L. (1980) Asa ati Ise Yoruba, Ibadan: University Press.

Olatunji O pado tun (2003) Iwe ati Iwe kiko Alatinuda (Atunse Kin-ni-ni), O yo ,

Excel Computer.

Olu Owolabi a.a.y. (2012) Ijinle Ede ati Litireso Yoruba Fun Ile-E ko

Se ko ndiri Agba, Iwe Keji, Ibadan: Evans Brothers (Nigeria Publishers)

Ltd.

Page 13: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

ODUN KETA SIME SITA KIN-IN-NI

EDU 311 KO MO-N-WO-O (KIRE DIITI 6) C

ODUN KE TA SIME SITA KEJI

YOR1 321 IMO SAYE NSI ATI E RO YORUBA (KIRE DIITI 1) E

Ise Aro, Aso-hihun, eni-hihun, oti pipon, ise ebu ose, ise adi sise, ise ebu

i koko abbl., ise isegun, awon arun ati itoju i.e. arun ajemo -ibalopo tako-tabo,

arunkogboogun eedi ati awon miiran; feto-so mo-bibi, magun, teso o , aabo,

oyun dide abbl., ito ju alaboyun ati igbe bi abbl.

REF: Ilesanmi, T. M. (1989). Ile-Ife : Obafe mi Awolowo University Press Ltd.

Ogunranti, J. I. (2006). E ko Ise nbaye. Lagos: Kingson Publishers.

Olajubu, O. (1981). Iwe Asa Ibile Yoruba. Iadan: The Caxton Press (W. A.)

Ltd.

Fadipe , N. A. (1970). The Sociology of Yoruba. Ibadan: University of

Ibadan Press.

Ogunranti, J. I. (2019). “Ise Abinibi Yoruba” Ninu Ede, Litireso ati Asa

Yoruba. Ibadan: Masterprint Publishers (Coming out soon)

Fabarebo , S. I. ati Raji, S. M. (2010). “Agbeye wo Ise Awon Asaaju Lori

Magun”. E gin: Jo na Ise Akada Ni Ede Yoruba, pp. 61 – 73.

YOR1 322 EWI APILE KO ATI AWON AKEWI YORUBA (KIRE DIITI 2) C

Ohun ti Ewi Apileko Yoruba je

Eya Ewi Apileko Yoruba

Aato

Koko-o ro

Kiko ako jinle lori awon akewi meji-saaju ominira, le yin ominira ati aromogba

(Tako-tabo)

Àjànàkú Ztzr7 (1998) . Orin Ewúro. Ìbàdàn: Sam Bookam Publishers.

Ak7nj-gb8n, Ad3agbo. (1983) Ew8 *w0y7 Glasgow Collins.

Zlzbq Ol5gb9y4ga(1993). On7r5ur5 Zr0f= .*bzdzn: On7bon0j3 Press and Book Industries (Nig) .

Aw9ycl3 Oy4t5nd3 (1987). Ak3w8 L9 N’8tzn Apq Kej8 .Ibzdzn: On7b[n0j3 Press and Book Industries

Aw9ycl3 Oy4t5nd3 (1987). Ak3w8 L9 N’8tzn Apq K87nn7 .Ibzdzn. On7b[n0j3 Press and Book Industries

Zyzn9 Gb3mis9y4 (1995) Zk9j[p= Ew8 Gb2f1 *kcjz Lagos: Kqr9hunw7 Nigeria Enterprises Publishers and Entertainment Unit

Akinwumi Iso la (1978). Àfàìmo àti Àwon Àròfo Mìíràn. Ìbàdàn. Oxford University Press.

Page 14: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

{basq D3/rel3 Ad3t8m7kzn (1971). Zw[n Ak3w8 Apq K87nn7 Yor6bq Philosophy *bzdzn University Press

{basq D3/rel3 Ad3t8m7kzn(1971). *w3 Kej8 Zw[n Ak3w8 Yor6bq Philosophy *bzdzn General Publications Section Ministry of Education

{d5nj[, J.F. (1961). Zk9j[p= Ew8 Alqd6n. London: Longman

Olqb7mtqn Af[lqb7 (1969) Zqd[ta Zr0f= Lagos Macmillan Nigeria Publisher

{lqb7mtqn Af[lqb7 (1990) Aqyan Zw[n +m=rzn L9r7 *m= *j8nl2 Yor6bq Zp3r0 Kej8 ni 8rqnt7 J.F. {d5nj[ Yaba Lagos Nigeria J.F. {d5nj[ Memorial Lectures

Olábímtán, A. (1980). Ogbo n Ìtopinpin Ewì Yorùbá. Nigeria: Macmillan

{lqt5nj7 {lqt5nd3,O. (1982), Ad3bqy= Fql3t7 A Study of His Poems *bzdzn Heinemann Educational Books

{lqt5nj7 {lqt5nd3 .O. (1984) . Ad3j[k1 Arq *j7l4je Zk9j[p= *tzn k3k34k3 Ad3bqy= Fql3t7. *bzdzn: Heinemann Educational Books

{lqt5nj7 {lqt5nd3 .O. (1984) Features of Yor6bq Oral Poetry .*bzdzn: University Press

Ol5nlqd3 Tq7w0 . (1997) . Ak3w8 ? K3 Ol9t65 gbogbogb00, Tq7w0 Ol5nlqd3. Ol9t65 Lqs5nkznm7 T2l2 )xogbo Nigeria Sumob Publishers

Ol5rqnkinx1 {lqnip2kun (1987) *j8 Ay3. *bzdzn :On7b[n0j3 Press

)n7 D0kun (1980) . Zgb3l3k5. Il3xa: Dokun Oni Books

+pqd=tun T5nj7 (1986) . Ab1r1 Or9. *bzdzn: Vantage Publishers

+pqd=tun T5nj7 (1987) . Zr0f= El3w8 Od0. *bzdzn: On8b[n0j3 Press and Book Industries

Rqj7 S.M. (1991) . Winr7nwinr8n Cnu On7rqrz *bzdzn: On7b[n0j3 Press and Book Industries

Szng9t9y4 {lqd3l3 Abdullahi Aw0l5mqt21 zti Ad3s9y4 {m[lax[ye. (1991) Zzr0 M1ta *bzdzn: Evans Brothers

YOR1 323 ISE-GBIGBOORO LORI LITIRESO ALOHUN YORUBA (KIRE DIITI 2) C

Akojopo awon e ya alohun b.a. Ijala, Rara, Olele, Iye re -Ifa. Alamo , Biripo,

Ege abbl.

Itupale o ko o kan e ya b.a. Ekun iyawo, Alo -apamo , Etiyeri, Apala, Sakara abbl.

Ifisere orisiiris i awon eya yii

Amuse ise giriki ni iyara ife rokede ni a gbodo tepele mo

Àjànàkú Ztzr7 (1998) . Orin Ewúro. Ìbàdàn: Sam Bookam Publishers.

Ak7nj-gb8n, Ad3agbo. (1983) Ew8 *w0y7 Glasgow Collins.

Zlzbq Ol5gb9y4ga(1993). On7r5ur5 Zr0f= .*bzdzn: On7bon0j3 Press and Book Industries (Nig) .

Page 15: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

Aw9ycl3 Oy4t5nd3 (1987). Ak3w8 L9 N’8tzn Apq Kej8 .Ibzdzn: On7b[n0j3 Press and Book Industries

Aw9ycl3 Oy4t5nd3 (1987). Ak3w8 L9 N’8tzn Apq K87nn7 .Ibzdzn. On7b[n0j3 Press and Book Industries

Zyzn9 Gb3mis9y4 (1995) Zk9j[p= Ew8 Gb2f1 *kcjz Lagos: Kqr9hunw7 Nigeria Enterprises Publishers and Entertainment Unit

Akinwumi Isola (1978). Àfàìmo àti Àwon Àròfo Mìíràn. Ìbàdàn. Oxford University Press.

{basq D3/rel3 Ad3t8m7kzn (1971). Zw[n Ak3w8 Apq K87nn7 Yor6bq Philosophy *bzdzn University Press

{basq D3/rel3 Ad3t8m7kzn(1971). *w3 Kej8 Zw[n Ak3w8 Yor6bq Philosophy *bzdzn General Publications Section Ministry of Education

{d5nj[, J.F. (1961). Zk9j[p= Ew8 Alqd6n. London: Longman

Olqb7mtqn Af[lqb7 (1969) Zqd[ta Zr0f= Lagos Macmillan Nigeria Publisher

{lqb7mtqn Af[lqb7 (1990) Aqyan Zw[n +m=rzn L9r7 *m= *j8nl2 Yor6bq Zp3r0 Kej8 ni 8rqnt7 J.F. {d5nj[ Yaba Lagos Nigeria J.F. {d5nj[ Memorial Lectures

Olábímtán, A. (1980). Ogbo n Ìtopinpin Ewì Yorùbá. Nigeria: Macmillan

{lqt5nj7 {lqt5nd3,O. (1982), Ad3bqy= Fql3t7 A Study of His Poems *bzdzn Heinemann Educational Books

{lqt5nj7 {lqt5nd3 .O. (1984) . Ad3j[k1 Arq *j7l4je Zk9j[p= *tzn k3k34k3 Ad3bqy= Fql3t7. *bzdzn: Heinemann Educational Books

{lqt5nj7 {lqt5nd3 .O. (1984) Features of Yor6bq Oral Poetry .*bzdzn: University Press

Ol5nlqd3 Tq7w0 . (1997) . Ak3w8 ? K3 Ol9t65 gbogbogb00, Tq7w0 Ol5nlqd3. Ol9t65 Lqs5nkznm7 T2l2 )xogbo Nigeria Sumob Publishers

Ol5rqnkinx1 {lqnip2kun (1987) *j8 Ay3. *bzdzn :On7b[n0j3 Press

)n7 D0kun (1980) . Zgb3l3k5. Il3xa: Dokun Oni Books

+pqd=tun T5nj7 (1986) . Ab1r1 Or9. *bzdzn: Vantage Publishers

+pqd=tun T5nj7 (1987) . Zr0f= El3w8 Od0. *bzdzn: On8b[n0j3 Press and Book Industries

Press and Book Industries

Rqj7 S.M. (1991) . Winr7nwinr8n Cnu On7rqrz *bzdzn: On7b[n0j3 Press and Book Industries

Szng9t9y4 {lqd3l3 Abdullahi Aw0l5mqt21 zti Ad3s9y4 {m[lax[ye. (1991) Zzr0 M1ta *bzdzn: Evans Brothers

YOR1 324 IGBE-AYE ATI AWUJO YORUBA (KIRE DIITI 1) E

Eto iselu Awujo (Ebi, Ore sise, ati ajosepo pelu awon miiran)

Awon ounje abinibi ati eto ilana ounje jije

Isinku

Igbagbo Yoruba, eyi ni Eewoo , Oso ati Aje abbl

Page 16: COURSE OUTLINE AND REFERENCES NCE€¦ · COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO ÌLA-ÈRÒ FÚN ÈDÈ (YOR 1) ỌDÚN KÍN-IN-NÍ SIMESITA KIN-IN-NI

COURSE CONTENT FOR NCE YORUBA DEPARTMENT ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION, ONDO

Eto o ro -aje awujo Yoruba, eyi ni owo ti takotabo, oja tita abbl., irufe awon oja

ti won le pate, owo ati ipolowo oja

Onka ati isiro Yoruba.